Back to Browse

Brymo - Adèdótun (Lyrics)

22.7K views
Apr 13, 2022
3:29

#Adèdótun #Yellow by Brymo #Yellow #Lyrics Spotify: https://open.spotify.com/track/1gOpMJ5txyhHPBXt1dV1DC?si=1fac08789d9a4098 Adèdótun Lyrics: Awon adan n fo loke Won fonka soju orun Un o maa mo ibi won nlo Eledua lo n seke won Ko keyin si e Ore ooo Ohun o n wa O wa niwaju re ooo Adédòtun Oyindamola mi Ero gbogbo e ba n gberin Adédòtun ooo Awon adan n fo loke Nigba igba won kun oju orun Un o maa mo ohun wo n je Eledua lo n so won lo n bo won Ko pamo si e Ore ooo O wa lo Sokoto O waa lapo sokoto Adédòtun Oyindamola mi Ero gbogbo e ba n gberin Adédòtun ooo Adédòtun O ooo oyindamola mi Ero gbogbo e ba n gberin Adédòtun ooo Ko pa mo si e Ore ooo Ohun o n wa Owa niwaju re ooo ooo

Download

0 formats

No download links available.

Brymo - Adèdótun (Lyrics) | NatokHD