Back to Browse

Hymn 176

9.5K views
Aug 27, 2017
4:50

HYMN 176 Verse 1 Baba pa lase la t'orun wa ki gbogbo aiye si wariri Fun 'jo Mimo, la t'orun wa Ijo yi ni yio we aiye mo Aje Oso yio wa riri labe agbara mimo yi Awon Angeli si kun f'ayo Iyanu, f'oko Ikehin, Halleluyah fun ise Oluwa Verse 2 Igba ikehin na ti de Kristi Jesu yio pada wa Lati wa se 'dajo aiye Iku re lori agbelebu Eje ati omi to nsan Kuro ninu iha mimo re Ko gbodo lo sori asan Gbogbo oju yio si tun ri Pelu awon Angeli mimo re Verse 3 K'elese ronupiwada F'ojo iwariri nla na Awon Angeli yio fun ipe A o ka ile at'orun Okun yio d'ohun airi mo Awon oku yio ji dide Imiran pelu ayo nla Imiran pelu Ijiya Elese yio wariri lojo na Verse 4 Awon t'oku f'oro Kristi Awon t'oru Agbelebu re Nwon yio ji pelu ogo nla A o wo won laso Ogo A o de won lade wura Mariwo ope lowo won Won yio fo pade Kristi won are ki yio si fun won mo Halleluyah, li ohun orin won. (Amin)

Download

0 formats

No download links available.

Hymn 176 | NatokHD